Oorun ati osupa je aami meji ninu awon aamin Olohun oba ti ola re ga, Olohun maa nte  awon mejeeji ri nigbati o ba ri ese  ati iyapa ase re lodo awon eru re, ki awon eru lee seri pada si odo re ati ki won le ronupiwada kuro nibi awon ese won.
 Nitidajudaju, Olohun oba alekeola ti se irun iteri oorun tabi osupa lofin fun iruu isele yi, awon eru yio ke gbajare losi odo Olohun, won yio si wa iranlowo re, beeni Olohun yio ba re adanwo yi kuro fun won. 
ء.

Oorun ati osupa je aami meji ninu awon aamin Olohun oba ti ola re ga, Olohun maa nte awon mejeeji ri nigbati o ba ri ese ati iyapa ase re lodo awon eru re, ki awon eru lee seri pada si odo re ati ki won le ronupiwada kuro nibi awon ese won. Nitid ...

Ahon je idera kan ninu awon idera Olohun lori eru, o je dandan lori eru lati maa dupe idera yii pelu imaa so eto ti Olohun nibe, yio maa so kuro nibi ohun ti yio bi Olohun ninu, yio si maa tu sile nibi ohun ti yio yoo Olohun ninu. Atiwipe akolekan anabi(Ki ike ati ola Olohun maa baa) lori abala yii koja ohun ti a le fi enu so tan, dajudaju anabi ka siso ahon si ini gbogbo oore patapata, O si maa nse atenumo re fun awon ara ile re, paapaa julo, ohun ti o po julo ti o maa nmu awon eniyan wo ina ni itasegere ahon won, E yaa je ki a sora, E je ki a sora.

Ahon je idera kan ninu awon idera Olohun lori eru, o je dandan lori eru lati maa dupe idera yii pelu imaa so eto ti Olohun nibe, yio maa so kuro nibi ohun ti yio bi Olohun ninu, yio si maa tu sile nibi ohun ti yio yoo Olohun ninu. Atiwipe akolekan an ...

Osu Ramadan, osu aponle, ni osu yi ni a maa nsi  awon ilekun alijanna, a si maa nti awon ilekun ile ina, osu ti Olohun gbola fun lori gbogbo osu ti o ku, Olohun se ajulo oore fun awon eru re pelu re lati lee silekun afokante pelu ibokun ina kuro lorun, ti Olohun oba ni bibokun ina kuro ni gbogbo oru kookan ninu awon oru re, ohun ti o to fun awon onigbagbo ododo ni ipesesile fun osu alaponle yii, ati igbaradi fun-un siwaju ki o to de, osu yi je alejo abiyi ti kii wa bawa ni odun ayafi ni eekan soso.

Osu Ramadan, osu aponle, ni osu yi ni a maa nsi awon ilekun alijanna, a si maa nti awon ilekun ile ina, osu ti Olohun gbola fun lori gbogbo osu ti o ku, Olohun se ajulo oore fun awon eru re pelu re lati lee silekun afokante pelu ibokun ina kuro loru ...

Idaa okun ibi po je alaamori kan ti Olohun fi maa ngbooro arisiki, O si tun je okunfa emigigun, Olohun si maa nfi se ibukun dukia eniyan, idaibipo je apere pipee igbagbo ati didaa Islam eniyan, ni ida miran, ijakun ebi je okunfa ibidandan Olohun ati ijiya re, ati egbee ati iya, ti yio maa pa alubarika re, ti yio  si maa jogun  ota sise ati ikorira eni.

Idaa okun ibi po je alaamori kan ti Olohun fi maa ngbooro arisiki, O si tun je okunfa emigigun, Olohun si maa nfi se ibukun dukia eniyan, idaibipo je apere pipee igbagbo ati didaa Islam eniyan, ni ida miran, ijakun ebi je okunfa ibidandan Olohun ati ...

Ini igbagbo si awon oruko Olohun ati awon iroyin re je ipile kan ti o tobi ninu awon ipile esin, O si je okunfa kan ninu awon okunfa iwo alijanna eru, bakanna ni wipe, Olohun ti ola re ga ti gbee awon  eru longbe imaa bee ati imaa baa soro kelekele pelu awon oruko re ti o rewa ati awon iroyin re ti o ga, nitori idi eyi, o too fun musulumi lati ko awon oruko ati iroyin wonyii ati lati gbo itumo re ye yekeyeke.

Ini igbagbo si awon oruko Olohun ati awon iroyin re je ipile kan ti o tobi ninu awon ipile esin, O si je okunfa kan ninu awon okunfa iwo alijanna eru, bakanna ni wipe, Olohun ti ola re ga ti gbee awon eru longbe imaa bee ati imaa baa soro kelekele p ...