Olohun Oba ti ola re ga pa ase ki obinrin maa di gagaa ati idunnumo igbele won, O si kilo fun won nibi  irin ohoho ati imaa din ohun fun awon okunrin ki o le je iso fun won nibi ibaje sise, ati ilewonsa nibi awon okunfa fitinati. E ri ijade ni ohoho obinrin je aburu ti yio joba lori obinrin ati awujo patapata, ohun Kankan ki yio si da abo bo obinrin ju ibihoho ati itiju re.

Olohun Oba ti ola re ga pa ase ki obinrin maa di gagaa ati idunnumo igbele won, O si kilo fun won nibi irin ohoho ati imaa din ohun fun awon okunrin ki o le je iso fun won nibi ibaje sise, ati ilewonsa nibi awon okunfa fitinati. E ri ijade ni ohoho ...

Irun janmoo je ohun ti laada re po jaburata ju irun ti eniyan ba da ki ninu ile tabi soobu re lo,Anobi ki ike ati ola Olohun maa ba se alaye ije oranyan irun janmoo o si tun gbe awa omoleyinyin longbe lati moju too debi wipe Anobi gba afoju ti o wa beere lowa fun ede ni imoran wipe ki O ma lo ki irun re ni janmoo lodiwon ti o ba ti ngbon ipepe iru.

Irun janmoo je ohun ti laada re po jaburata ju irun ti eniyan ba da ki ninu ile tabi soobu re lo,Anobi ki ike ati ola Olohun maa ba se alaye ije oranyan irun janmoo o si tun gbe awa omoleyinyin longbe lati moju too debi wipe Anobi gba afoju ti o wa b ...

Suuru koni wo ohunkohun ayafi ki o ko oso ba nkan naa, beeni, ko ni kuro nibi nkan ayafi ki o ko abuku baa nkan naa.Musulumi gbodo je onisuuru nibi iwuwasi re, koda tofi mo wiwa ijeemu wa, a ko gbodo wa owo ojiji. eleyii ni Olohun fi pawa lase imaa wa iranlowo pelu suuru ati irun kiki.

Suuru koni wo ohunkohun ayafi ki o ko oso ba nkan naa, beeni, ko ni kuro nibi nkan ayafi ki o ko abuku baa nkan naa.Musulumi gbodo je onisuuru nibi iwuwasi re, koda tofi mo wiwa ijeemu wa, a ko gbodo wa owo ojiji. eleyii ni Olohun fi pawa lase imaa w ...

Igbarale Olohun Oba ti ola re ga je ohun ti a fe ti o tobi, o si je ase lati odo Olohun ti ola re ga fun awon eru re ti won je onigbagbo olodo, O si pa won lase re nibi gbogbo isesi pata. Igbarale Olohun ni ifiarati okan ti o je ti ododo le Olohun Oba ti o tobi ti o gbongbon nibi fifa daadaa ati titi aburu danu, ti o ba je wipe eru gbe ara le Olohun ni igbarale otito ni, Olohun ko ba too, ko ba si se ipese fun gegebii O ti npese fun eye ati awon eranko.

Igbarale Olohun Oba ti ola re ga je ohun ti a fe ti o tobi, o si je ase lati odo Olohun ti ola re ga fun awon eru re ti won je onigbagbo olodo, O si pa won lase re nibi gbogbo isesi pata. Igbarale Olohun ni ifiarati okan ti o je ti ododo le Olohun Ob ...

Alukurani je tiira Olohun eleyii ti o sokale lati odo re lati maa je iwe ti yio maa dari gbogbo olugbagbo ododo nibi isemi aye ati esin won, eniti o ba gbe iwe mimo yii siwaju ti o si ntele, iwe yi yio fa iru enibee wo Alijannah Onidera.Nida miran, eniti o ba ju iwe mimo yi seyin ti ko tele, iwe yii yio ti iru eniti bee woo ina, latiara idieyi, eniti o ba nwa oore aye ati orun, ki o ya gba iwe mimo yii mu ki o si maa ka ni oore koore.

Alukurani je tiira Olohun eleyii ti o sokale lati odo re lati maa je iwe ti yio maa dari gbogbo olugbagbo ododo nibi isemi aye ati esin won, eniti o ba gbe iwe mimo yii siwaju ti o si ntele, iwe yi yio fa iru enibee wo Alijannah Onidera.Nida miran, e ...