Melomelo omoniyan ti o ti ileere jade ti o di idakuda lati ara ore ti o yan ni aayo,  ore daadaa yio maa gbani ni iyanju daadaa sise, ni idakeji, ore aburu koni gbani ni yanju nkankan ti o ju aburu lo,lati ara idi eyii, ni Islam fi se wa ni ojukokoro yiyan ore ti o je eniire.

Melomelo omoniyan ti o ti ileere jade ti o di idakuda lati ara ore ti o yan ni aayo, ore daadaa yio maa gbani ni iyanju daadaa sise, ni idakeji, ore aburu koni gbani ni yanju nkankan ti o ju aburu lo,lati ara idi eyii, ni Islam fi se wa ni ojukokoro ...

Ninu ohun ti anobi so asoole re fun awa alhummah re ni wipe ki a sora fun aye ati obinrin, Ojise Olohun ko sadede wi bee bikose wipe o fe gba awa ijo re kuro nibi fitinah ti obinrin le ko bani ni.Ti o ba ri bee, e jae ki a sora nibe.

Ninu ohun ti anobi so asoole re fun awa alhummah re ni wipe ki a sora fun aye ati obinrin, Ojise Olohun ko sadede wi bee bikose wipe o fe gba awa ijo re kuro nibi fitinah ti obinrin le ko bani ni.Ti o ba ri bee, e jae ki a sora nibe.

Ododo je iwa olola ninu ohun ti o maa npe igbagbo, ti o si maa npe Islam, nigbati Olohun Oba ti ola re ga paa ni ase, O si tun  se eyin fun awon ti won ba gba iroyin pelu re, iwa ododo je ola fun awon olododo, o si je oso ati itutu oju fun eniti o ba jere pelu re. Nidamiran, iro je apejuwe ijanba ti o tobi, paapaa julo, o wa ninu  awon apere pooki, ki yio si le eru kun ju ijinna si Olohun lo, eru ko ni ye ni eniti yio maa so ododo titi ti won yio fi ko fun lodo Olohun wipe olododo ni, eru ko si ni ye ni imaa pa iro titi ti won yio fi ko lodo Olohun wipe okuro ni.

Ododo je iwa olola ninu ohun ti o maa npe igbagbo, ti o si maa npe Islam, nigbati Olohun Oba ti ola re ga paa ni ase, O si tun se eyin fun awon ti won ba gba iroyin pelu re, iwa ododo je ola fun awon olododo, o si je oso ati itutu oju fun eniti o ba ...

Imo je imole ati onaamo, aimokan si je okunkun ati anu, imo pelu igbagbo je agbega laye ati lorun, lilo imo ni eso re, ohun si ni ipinle imo ati erongba lori re, o je oranyan lori awon akeeko imo ki won maa sise too ohun ti won mo, ti won ba se bee, imo naa yio je abamo ati adanu fun won, onimimo ti kii ba lo imo re da gegebii abela ti o ntan imonle fun awon eniyan ti o si yo ara re.

Imo je imole ati onaamo, aimokan si je okunkun ati anu, imo pelu igbagbo je agbega laye ati lorun, lilo imo ni eso re, ohun si ni ipinle imo ati erongba lori re, o je oranyan lori awon akeeko imo ki won maa sise too ohun ti won mo, ti won ba se bee, ...

Ojo jimoh je ojo ti o loore julo ninu ojo ti oorun nran nibe, ojo yii ni Olohun daa anabi Adamo, ojo yi si ni asiko igbende yio sele, o je ojo odun fun awon musulumi, lati idi eyi ni a se se awon alaamori kan lofin nibe, lara re ni; khutubah jimoh, iwe ati ifin lofinda oloorun didun sara, ati wiwo aso ti o rewa julo lo kii ati irisi ti o pe julo ati imaagbe oruko Olohun tobi nigbati a ba nlo kii, ati isunmo imaamu, ati ipa okan po lati gbo waasi ati irannileti.

Ojo jimoh je ojo ti o loore julo ninu ojo ti oorun nran nibe, ojo yii ni Olohun daa anabi Adamo, ojo yi si ni asiko igbende yio sele, o je ojo odun fun awon musulumi, lati idi eyi ni a se se awon alaamori kan lofin nibe, lara re ni; khutubah jimoh, i ...